Ìsíkíẹ́lì 33:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Wọn yóò rọ́ wá bá ọ, kí wọ́n lè jókòó síwájú rẹ bí èèyàn mi; wọ́n á sì gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ, àmọ́ wọn ò ní ṣe ohun tí wọ́n gbọ́.+ Wọ́n ń fi ẹnu wọn sọ̀rọ̀ dídùn fún ọ,* àmọ́ bí wọ́n ṣe máa jèrè tí kò tọ́ ló wà lọ́kàn wọn.
31 Wọn yóò rọ́ wá bá ọ, kí wọ́n lè jókòó síwájú rẹ bí èèyàn mi; wọ́n á sì gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ, àmọ́ wọn ò ní ṣe ohun tí wọ́n gbọ́.+ Wọ́n ń fi ẹnu wọn sọ̀rọ̀ dídùn fún ọ,* àmọ́ bí wọ́n ṣe máa jèrè tí kò tọ́ ló wà lọ́kàn wọn.