ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 9:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Torí àwọn èèyàn náà kò tíì pa dà sọ́dọ̀ Ẹni tó ń lù wọ́n;

      Wọn ò wá Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun.+

  • Jeremáyà 5:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Jèhófà, ǹjẹ́ kì í ṣe àwọn olóòótọ́ ni ojú rẹ ń wò?+

      O lù wọ́n, ṣùgbọ́n wọn ò mọ̀ ọ́n lára.*

      O pa wọ́n run, àmọ́ wọn ò gba ìbáwí.+

      Wọ́n mú ojú wọn le ju àpáta lọ,+

      Wọn kò sì yí pa dà.+

  • Hósíà 7:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Àwọn àjèjì ti gba okun rẹ̀ tán,+ ṣùgbọ́n kò mọ̀.

      Irun orí rẹ̀ ti di funfun, síbẹ̀ kò kíyè sí i.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́