Diutarónómì 7:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́ torí pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ yín, tó sì ṣe ohun tó búra fún àwọn baba ńlá yín+ pé òun máa ṣe ni Jèhófà ṣe fi ọwọ́ agbára mú yín kúrò, kó lè rà yín pa dà kúrò ní ilé ẹrú,+ kúrò lọ́wọ́* Fáráò ọba Íjíbítì. Jeremáyà 31:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà ti fara hàn mí láti ọ̀nà jíjìn, ó sì sọ pé: “Ìfẹ́ tí mo ní sí ọ jẹ́ ìfẹ́ ayérayé. Ìdí nìyẹn tí mo fi fà ọ́ mọ́ra pẹ̀lú ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.*+
8 Àmọ́ torí pé Jèhófà nífẹ̀ẹ́ yín, tó sì ṣe ohun tó búra fún àwọn baba ńlá yín+ pé òun máa ṣe ni Jèhófà ṣe fi ọwọ́ agbára mú yín kúrò, kó lè rà yín pa dà kúrò ní ilé ẹrú,+ kúrò lọ́wọ́* Fáráò ọba Íjíbítì.
3 Jèhófà ti fara hàn mí láti ọ̀nà jíjìn, ó sì sọ pé: “Ìfẹ́ tí mo ní sí ọ jẹ́ ìfẹ́ ayérayé. Ìdí nìyẹn tí mo fi fà ọ́ mọ́ra pẹ̀lú ìfẹ́ tí kì í yẹ̀.*+