ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 13:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Ní ọ̀sán, Jèhófà máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n ìkùukùu* kó lè máa darí wọn lójú ọ̀nà,+ àmọ́ ní òru, ó máa ń lọ níwájú wọn nínú ọwọ̀n iná* kó lè fún wọn ní ìmọ́lẹ̀, kí wọ́n lè máa bá ìrìn àjò wọn lọ tọ̀sántòru.+

  • Nọ́ńbà 9:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ní ọjọ́ tí wọ́n to+ àgọ́ ìjọsìn, ìkùukùu* bo àgọ́ ìjọsìn náà, ìyẹn àgọ́ Ẹ̀rí, àmọ́ láti ìrọ̀lẹ́ títí di àárọ̀,+ ohun tó rí bí iná wà lórí àgọ́ ìjọsìn náà.

  • Sekaráyà 2:4, 5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Ó wá sọ fún un pé: “Sáré lọ síbẹ̀ yẹn, kí o sì sọ fún ọkùnrin yẹn pé, ‘“Wọn yóò gbé inú Jerúsálẹ́mù+ bí ìgbèríko gbalasa,* nítorí gbogbo èèyàn àti ẹran ọ̀sìn tó máa wà nínú rẹ̀.”+ 5 Jèhófà kéde pé, “Èmi yóò di ògiri iná fún un yí ká,+ màá sì mú kí ògo mi wà láàárín rẹ̀.”’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́