Àìsáyà 44:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ má ṣe jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá yín,Ẹ má sì jẹ́ kí ìbẹ̀rù sọ ọkàn yín domi.+ Ṣebí mo ti sọ fún ẹnì kọ̀ọ̀kan yín ṣáájú, tí mo sì kéde rẹ̀? Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi.+ Ṣé Ọlọ́run kankan wà yàtọ̀ sí mi ni? Rárá, kò sí Àpáta míì;+ mi ò mọ ìkankan.’”
8 Ẹ má ṣe jẹ́ kí jìnnìjìnnì bá yín,Ẹ má sì jẹ́ kí ìbẹ̀rù sọ ọkàn yín domi.+ Ṣebí mo ti sọ fún ẹnì kọ̀ọ̀kan yín ṣáájú, tí mo sì kéde rẹ̀? Ẹ̀yin ni ẹlẹ́rìí mi.+ Ṣé Ọlọ́run kankan wà yàtọ̀ sí mi ni? Rárá, kò sí Àpáta míì;+ mi ò mọ ìkankan.’”