-
Àìsáyà 45:1, 2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+
Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+
Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+
Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,
Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,
Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè:
Màá fọ́ àwọn ilẹ̀kùn bàbà sí wẹ́wẹ́,
Màá sì gé àwọn ọ̀pá irin lulẹ̀.+
-