Ẹ́kísódù 15:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ó ti ju àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin Fáráò àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sínú òkun,+ Àwọn tó dára jù nínú àwọn jagunjagun rẹ̀ sì ti rì sínú Òkun Pupa.+
4 Ó ti ju àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin Fáráò àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sínú òkun,+ Àwọn tó dára jù nínú àwọn jagunjagun rẹ̀ sì ti rì sínú Òkun Pupa.+