Àìsáyà 42:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wò ó, àwọn nǹkan àkọ́kọ́ ti ṣẹlẹ̀;Ní báyìí, mò ń kéde àwọn nǹkan tuntun. Kí wọ́n tó rú yọ, mo sọ fún yín nípa wọn.”+
9 Wò ó, àwọn nǹkan àkọ́kọ́ ti ṣẹlẹ̀;Ní báyìí, mò ń kéde àwọn nǹkan tuntun. Kí wọ́n tó rú yọ, mo sọ fún yín nípa wọn.”+