Àìsáyà 64:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Kò sẹ́ni tó ń pe orúkọ rẹ,Kò sẹ́ni tó ń ru ara rẹ̀ sókè láti gbá ọ mú,Torí o ti fi ojú rẹ pa mọ́ fún wa,+O sì mú ká ṣègbé* torí* ẹ̀ṣẹ̀ wa.
7 Kò sẹ́ni tó ń pe orúkọ rẹ,Kò sẹ́ni tó ń ru ara rẹ̀ sókè láti gbá ọ mú,Torí o ti fi ojú rẹ pa mọ́ fún wa,+O sì mú ká ṣègbé* torí* ẹ̀ṣẹ̀ wa.