Àìsáyà 32:14, 15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí wọ́n ti pa ilé gogoro tó láàbò tì;Wọ́n ti pa ìlú aláriwo tì.+ Ófélì+ àti ilé ìṣọ́ ti di ahoro títí láé,Ààyò àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó,Ibi ìjẹko àwọn agbo ẹran,+15 Títí dìgbà tí a bá tú ẹ̀mí jáde sórí wa látòkè,+Tí aginjù di ọgbà eléso,Tí a sì ka ọgbà eléso sí igbó.+
14 Torí wọ́n ti pa ilé gogoro tó láàbò tì;Wọ́n ti pa ìlú aláriwo tì.+ Ófélì+ àti ilé ìṣọ́ ti di ahoro títí láé,Ààyò àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ igbó,Ibi ìjẹko àwọn agbo ẹran,+15 Títí dìgbà tí a bá tú ẹ̀mí jáde sórí wa látòkè,+Tí aginjù di ọgbà eléso,Tí a sì ka ọgbà eléso sí igbó.+