Àìsáyà 46:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ẹ rántí àwọn nǹkan àtijọ́* tó ti wà tipẹ́,Pé èmi ni Ọlọ́run,* kò sí ẹlòmíì,Èmi ni Ọlọ́run, kò sí ẹni tó dà bí èmi.+
9 Ẹ rántí àwọn nǹkan àtijọ́* tó ti wà tipẹ́,Pé èmi ni Ọlọ́run,* kò sí ẹlòmíì,Èmi ni Ọlọ́run, kò sí ẹni tó dà bí èmi.+