Hósíà 10:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 “Ísírẹ́lì jẹ́ igi àjàrà tí kò dáa* tó ń so èso.+ Bí èso rẹ̀ ṣe ń pọ̀ sí i, bẹ́ẹ̀ ló ń mú kí àwọn pẹpẹ rẹ̀ pọ̀ sí i;+Bí ilẹ̀ rẹ̀ ṣe ń méso jáde, bẹ́ẹ̀ ló ń mú kí àwọn ọwọ̀n òrìṣà rẹ̀ dára sí i.+
10 “Ísírẹ́lì jẹ́ igi àjàrà tí kò dáa* tó ń so èso.+ Bí èso rẹ̀ ṣe ń pọ̀ sí i, bẹ́ẹ̀ ló ń mú kí àwọn pẹpẹ rẹ̀ pọ̀ sí i;+Bí ilẹ̀ rẹ̀ ṣe ń méso jáde, bẹ́ẹ̀ ló ń mú kí àwọn ọwọ̀n òrìṣà rẹ̀ dára sí i.+