Jeremáyà 10:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Wọ́n dà bí aṣọ́komásùn tó wà nínú oko kùkúńbà,* wọn ò lè sọ̀rọ̀;+Ńṣe là ń gbé wọn, torí wọn ò lè rìn.+ Má bẹ̀rù wọn, torí wọn ò lè pani lára,Bẹ́ẹ̀ ni wọn ò lè ṣeni lóore kankan.”+ Ìṣe 19:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Ní báyìí, ẹ ti rí i, ẹ sì ti gbọ́ bí Pọ́ọ̀lù yìí ṣe yí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lérò pa dà, tó sì mú kí wọ́n ní èrò míì, kì í ṣe ní Éfésù nìkan,+ àmọ́ ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ ní gbogbo ìpínlẹ̀ Éṣíà, tó ń sọ pé àwọn ọlọ́run tí a fi ọwọ́ ṣe kì í ṣe ọlọ́run.+
5 Wọ́n dà bí aṣọ́komásùn tó wà nínú oko kùkúńbà,* wọn ò lè sọ̀rọ̀;+Ńṣe là ń gbé wọn, torí wọn ò lè rìn.+ Má bẹ̀rù wọn, torí wọn ò lè pani lára,Bẹ́ẹ̀ ni wọn ò lè ṣeni lóore kankan.”+
26 Ní báyìí, ẹ ti rí i, ẹ sì ti gbọ́ bí Pọ́ọ̀lù yìí ṣe yí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èèyàn lérò pa dà, tó sì mú kí wọ́n ní èrò míì, kì í ṣe ní Éfésù nìkan,+ àmọ́ ó fẹ́rẹ̀ẹ́ jẹ́ ní gbogbo ìpínlẹ̀ Éṣíà, tó ń sọ pé àwọn ọlọ́run tí a fi ọwọ́ ṣe kì í ṣe ọlọ́run.+