Àìsáyà 40:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ó mú igi láti fi ṣe ọrẹ,+Igi tí kò ní jẹrà. Ó wá oníṣẹ́ ọnà tó já fáfá,Láti ṣe ère gbígbẹ́ tí kò ní ṣubú.+ Jeremáyà 10:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Àṣà àwọn èèyàn náà jẹ́ ẹ̀tàn.* Igi igbó lásán ni wọ́n gé lulẹ̀,Ohun tí oníṣẹ́ ọnà fi irin iṣẹ́* gbẹ́ ni.+
20 Ó mú igi láti fi ṣe ọrẹ,+Igi tí kò ní jẹrà. Ó wá oníṣẹ́ ọnà tó já fáfá,Láti ṣe ère gbígbẹ́ tí kò ní ṣubú.+
3 Àṣà àwọn èèyàn náà jẹ́ ẹ̀tàn.* Igi igbó lásán ni wọ́n gé lulẹ̀,Ohun tí oníṣẹ́ ọnà fi irin iṣẹ́* gbẹ́ ni.+