Jeremáyà 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà, ǹjẹ́ kì í ṣe àwọn olóòótọ́ ni ojú rẹ ń wò?+ O lù wọ́n, ṣùgbọ́n wọn ò mọ̀ ọ́n lára.* O pa wọ́n run, àmọ́ wọn ò gba ìbáwí.+ Wọ́n mú ojú wọn le ju àpáta lọ,+Wọn kò sì yí pa dà.+
3 Jèhófà, ǹjẹ́ kì í ṣe àwọn olóòótọ́ ni ojú rẹ ń wò?+ O lù wọ́n, ṣùgbọ́n wọn ò mọ̀ ọ́n lára.* O pa wọ́n run, àmọ́ wọn ò gba ìbáwí.+ Wọ́n mú ojú wọn le ju àpáta lọ,+Wọn kò sì yí pa dà.+