Àìsáyà 44:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun: ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+ Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+
6 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí,Ọba Ísírẹ́lì+ àti Olùtúnrà rẹ̀,+ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun: ‘Èmi ni ẹni àkọ́kọ́ àti ẹni ìkẹyìn.+ Kò sí Ọlọ́run kankan àfi èmi.+