Àìsáyà 61:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Wọ́n máa tún àwọn ibi tó ti pa run nígbà àtijọ́ kọ́;Wọ́n máa kọ́ àwọn ibi tó ti dahoro nígbà àtijọ́,+Wọ́n sì máa mú kí àwọn ìlú tó ti pa run pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀,+Àwọn ibi tó ti wà ní ahoro láti ìran dé ìran.+
4 Wọ́n máa tún àwọn ibi tó ti pa run nígbà àtijọ́ kọ́;Wọ́n máa kọ́ àwọn ibi tó ti dahoro nígbà àtijọ́,+Wọ́n sì máa mú kí àwọn ìlú tó ti pa run pa dà sí bó ṣe wà tẹ́lẹ̀,+Àwọn ibi tó ti wà ní ahoro láti ìran dé ìran.+