Àìsáyà 48:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ sún mọ́ mi, kí ẹ sì gbọ́ èyí. Láti ìbẹ̀rẹ̀, mi ò sọ̀rọ̀ ní ìkọ̀kọ̀.+ Látìgbà tó ti ṣẹlẹ̀ ni mo ti wà níbẹ̀.” Ní báyìí, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti rán mi àti* ẹ̀mí rẹ̀.
16 Ẹ sún mọ́ mi, kí ẹ sì gbọ́ èyí. Láti ìbẹ̀rẹ̀, mi ò sọ̀rọ̀ ní ìkọ̀kọ̀.+ Látìgbà tó ti ṣẹlẹ̀ ni mo ti wà níbẹ̀.” Ní báyìí, Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ ti rán mi àti* ẹ̀mí rẹ̀.