Àìsáyà 1:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Tí kì í bá ṣe pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun dá díẹ̀ nínú wa sí,À bá ti dà bíi Sódómù gẹ́lẹ́,À bá sì ti jọ Gòmórà.+
9 Tí kì í bá ṣe pé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun dá díẹ̀ nínú wa sí,À bá ti dà bíi Sódómù gẹ́lẹ́,À bá sì ti jọ Gòmórà.+