ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Àwọn Ọba 18:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Torí náà, wọ́n mú akọ ọmọ màlúù tí wọ́n yàn, wọ́n ṣètò rẹ̀, wọ́n sì ń pe orúkọ Báálì láti àárọ̀ títí di ọ̀sán, wọ́n ń sọ pé: “Báálì, dá wa lóhùn!” Ṣùgbọ́n wọn ò gbọ́ ohùn kankan, ẹnì kankan ò sì dá wọn lóhùn.+ Wọ́n sì ń tiro yí ká pẹpẹ tí wọ́n ṣe.

  • Àìsáyà 37:37, 38
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 Torí náà, Senakérúbù ọba Ásíríà kúrò níbẹ̀, ó pa dà sí Nínéfè,+ ó sì ń gbé ibẹ̀.+ 38 Bó ṣe ń forí balẹ̀ ní ilé* Nísírọ́kì ọlọ́run rẹ̀, àwọn ọmọ rẹ̀, Adiramélékì àti Ṣárésà fi idà pa á,+ wọ́n sì sá lọ sí ilẹ̀ Árárátì.+ Esari-hádónì+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

  • Jónà 1:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Ẹ̀rù ba àwọn atukọ̀ òkun náà gan-an, kálukú wọn sì bẹ̀rẹ̀ sí í ké pe ọlọ́run rẹ̀ pé kó ran òun lọ́wọ́. Ni wọ́n bá ń ju àwọn nǹkan tó wà nínú ọkọ̀ náà sínú òkun, kó lè fúyẹ́.+ Àmọ́ Jónà ti lọ dùbúlẹ̀ sí ìsàlẹ̀ ọkọ̀* náà, ó sì ti sùn lọ fọnfọn.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́