-
1 Àwọn Ọba 21:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Gbàrà tí Jésíbẹ́lì gbọ́ pé wọ́n ti sọ Nábótì lókùúta pa, ó sọ fún Áhábù pé: “Dìde, lọ gba ọgbà àjàrà Nábótì ará Jésírẹ́lì,+ tí ó kọ̀ láti tà fún ọ, nítorí Nábótì kò sí láàyè mọ́. Ó ti kú.” 16 Bí Áhábù ṣe gbọ́ pé Nábótì ti kú, ó dìde, ó sì lọ sí ọgbà àjàrà Nábótì ará Jésírẹ́lì láti gbà á.
-