Ìfihàn 18:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Wọ́n máa dúró ní òkèèrè torí bó ṣe ń joró bà wọ́n lẹ́rù, wọ́n á sì sọ pé, ‘Ó mà ṣe o, ó mà ṣe o, Bábílónì, ìwọ ìlú ńlá,+ ìwọ ìlú tó lágbára, torí ìdájọ́ rẹ dé ní wákàtí kan!’
10 Wọ́n máa dúró ní òkèèrè torí bó ṣe ń joró bà wọ́n lẹ́rù, wọ́n á sì sọ pé, ‘Ó mà ṣe o, ó mà ṣe o, Bábílónì, ìwọ ìlú ńlá,+ ìwọ ìlú tó lágbára, torí ìdájọ́ rẹ dé ní wákàtí kan!’