Àìsáyà 52:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 52 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,+ ìwọ Síónì!+ Wọ aṣọ rẹ tó rẹwà,+ ìwọ Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́! Torí ẹni tí kò dádọ̀dọ́* àti aláìmọ́ kò ní wọ inú rẹ mọ́.+
52 Jí! Jí! Gbé agbára wọ̀,+ ìwọ Síónì!+ Wọ aṣọ rẹ tó rẹwà,+ ìwọ Jerúsálẹ́mù, ìlú mímọ́! Torí ẹni tí kò dádọ̀dọ́* àti aláìmọ́ kò ní wọ inú rẹ mọ́.+