Àìsáyà 45:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè:
45 Ohun tí Jèhófà sọ fún ẹni tó yàn nìyí, fún Kírúsì,+Ẹni tí mo di ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ mú,+Láti tẹ àwọn orílẹ̀-èdè lórí ba níwájú rẹ̀,+Láti gba ohun ìjà* àwọn ọba,Láti ṣí àwọn ilẹ̀kùn aláwẹ́ méjì níwájú rẹ̀,Kí wọ́n má sì ti àwọn ẹnubodè: