ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 22:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Áńgẹ́lì Jèhófà tún pe Ábúráhámù lẹ́ẹ̀kejì láti ọ̀run,

  • Jẹ́nẹ́sísì 22:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 ó dájú pé màá bù kún ọ, ó sì dájú pé màá mú kí ọmọ* rẹ pọ̀ bí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti iyanrìn etí òkun,+ ọmọ* rẹ yóò sì gba ẹnubodè* àwọn ọ̀tá+ rẹ̀ lọ́wọ́ wọn.

  • Jeremáyà 33:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Bí a kò ti lè ka àwọn ọmọ ogun ọ̀run, tí a kò sì lè wọn iyanrìn òkun, bẹ́ẹ̀ ni màá sọ àtọmọdọ́mọ* Dáfídì ìránṣẹ́ mi àti àwọn ọmọ Léfì tí wọ́n ń ṣe ìránṣẹ́ fún mi di púpọ̀.’”

  • Hósíà 1:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Iye àwọn èèyàn* Ísírẹ́lì máa dà bí iyanrìn òkun tí a kò lè díwọ̀n tàbí tí a kò lè kà.+ Níbi tí a ti sọ fún wọn pé, ‘Ẹ kì í ṣe èèyàn mi,’+ a ó pè wọ́n ní, ‘Àwọn ọmọ Ọlọ́run alààyè.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́