Àìsáyà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ní ọjọ́ yẹn, ó dájú pé o máa sọ pé: “Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà,Torí bó tiẹ̀ jẹ́ pé o bínú sí mi,Ìbínú rẹ ti wá rọlẹ̀, o sì tù mí nínú.+ Àìsáyà 40:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 40 “Ẹ tu àwọn èèyàn mi nínú, ẹ tù wọ́n nínú,” ni Ọlọ́run yín wí.+ Àìsáyà 66:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí ìyá ṣe ń tu ọmọ rẹ̀ nínú,Bẹ́ẹ̀ ni màá máa tù yín nínú;+Ẹ sì máa rí ìtùnú torí Jerúsálẹ́mù.+
12 Ní ọjọ́ yẹn, ó dájú pé o máa sọ pé: “Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ, Jèhófà,Torí bó tiẹ̀ jẹ́ pé o bínú sí mi,Ìbínú rẹ ti wá rọlẹ̀, o sì tù mí nínú.+