Mátíù 13:54 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 54 Lẹ́yìn tó dé agbègbè ìlú rẹ̀,+ ó bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ wọn nínú sínágọ́gù wọn, débi pé ó yà wọ́n lẹ́nu, wọ́n sì sọ pé: “Ibo ni ọkùnrin yìí ti rí ọgbọ́n yìí àti àwọn iṣẹ́ agbára yìí?+
54 Lẹ́yìn tó dé agbègbè ìlú rẹ̀,+ ó bẹ̀rẹ̀ sí í kọ́ wọn nínú sínágọ́gù wọn, débi pé ó yà wọ́n lẹ́nu, wọ́n sì sọ pé: “Ibo ni ọkùnrin yìí ti rí ọgbọ́n yìí àti àwọn iṣẹ́ agbára yìí?+