Mátíù 26:67 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 67 Wọ́n wá tutọ́ sí i lójú,+ wọ́n sì gbá a ní ẹ̀ṣẹ́.+ Àwọn míì gbá a lójú,+ Máàkù 14:65 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 65 Àwọn kan wá bẹ̀rẹ̀ sí í tutọ́ sí i lára,+ wọ́n sì bo ojú rẹ̀, wọ́n gbá a ní ẹ̀ṣẹ́, wọ́n sì ń sọ fún un pé: “Sọ tẹ́lẹ̀!” Wọ́n gbá a lójú, àwọn òṣìṣẹ́ ilé ẹjọ́ sì mú un.+ Lúùkù 22:63 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 63 Àwọn ọkùnrin tó mú Jésù wá bẹ̀rẹ̀ sí í fi Jésù ṣe yẹ̀yẹ́,+ wọ́n ń lù ú;+ Jòhánù 18:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, ọ̀kan nínú àwọn aláṣẹ tó dúró nítòsí gbá Jésù létí,+ ó sì sọ pé: “Ṣé bí o ṣe máa dá olórí àlùfáà lóhùn nìyẹn?”
65 Àwọn kan wá bẹ̀rẹ̀ sí í tutọ́ sí i lára,+ wọ́n sì bo ojú rẹ̀, wọ́n gbá a ní ẹ̀ṣẹ́, wọ́n sì ń sọ fún un pé: “Sọ tẹ́lẹ̀!” Wọ́n gbá a lójú, àwọn òṣìṣẹ́ ilé ẹjọ́ sì mú un.+
22 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, ọ̀kan nínú àwọn aláṣẹ tó dúró nítòsí gbá Jésù létí,+ ó sì sọ pé: “Ṣé bí o ṣe máa dá olórí àlùfáà lóhùn nìyẹn?”