Ẹ́kísódù 19:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Ẹ ó di ìjọba àwọn àlùfáà àti orílẹ̀-èdè mímọ́ fún mi.’+ Ohun tí ìwọ yóò sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nìyẹn.” Diutarónómì 7:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà Ọlọ́run yín sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+
6 Ẹ ó di ìjọba àwọn àlùfáà àti orílẹ̀-èdè mímọ́ fún mi.’+ Ohun tí ìwọ yóò sọ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì nìyẹn.”
6 Torí èèyàn mímọ́ lẹ jẹ́ fún Jèhófà Ọlọ́run yín, Jèhófà Ọlọ́run yín sì ti yàn yín kí ẹ lè di èèyàn rẹ̀, ohun ìní rẹ̀ pàtàkì,* nínú gbogbo èèyàn tó wà láyé.+