Àìsáyà 50:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Wò ó! Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ máa ràn mí lọ́wọ́. Ta ló máa sọ pé mo jẹ̀bi? Wò ó! Gbogbo wọn máa gbó bí aṣọ. Òólá* ló máa jẹ wọ́n run.
9 Wò ó! Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ máa ràn mí lọ́wọ́. Ta ló máa sọ pé mo jẹ̀bi? Wò ó! Gbogbo wọn máa gbó bí aṣọ. Òólá* ló máa jẹ wọ́n run.