Àìsáyà 45:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Àmọ́ Jèhófà máa gba Ísírẹ́lì là, ìgbàlà náà sì máa jẹ́ títí láé.+ Ojú ò ní tì yín, ìtìjú ò sì ní bá yín títí ayé.+ Lúùkù 1:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 àti pé láti ìran dé ìran, ó ń ṣàánú àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀.+
17 Àmọ́ Jèhófà máa gba Ísírẹ́lì là, ìgbàlà náà sì máa jẹ́ títí láé.+ Ojú ò ní tì yín, ìtìjú ò sì ní bá yín títí ayé.+