Sáàmù 106:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Ó bá Òkun Pupa wí, ó sì gbẹ;Ó mú wọn gba ìsàlẹ̀ rẹ̀ bí ẹni gba aṣálẹ̀* kọjá;+