Ìsíkíẹ́lì 14:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 “Torí ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Bó ṣe máa rí nìyẹn, nígbà tí mo bá fi oríṣi ìyà mẹ́rin*+ jẹ Jerúsálẹ́mù, ìyẹn idà, ìyàn, àwọn ẹranko burúkú àti àjàkálẹ̀ àrùn,+ kí n lè pa èèyàn àti ẹranko inú rẹ̀ run.+
21 “Torí ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Bó ṣe máa rí nìyẹn, nígbà tí mo bá fi oríṣi ìyà mẹ́rin*+ jẹ Jerúsálẹ́mù, ìyẹn idà, ìyàn, àwọn ẹranko burúkú àti àjàkálẹ̀ àrùn,+ kí n lè pa èèyàn àti ẹranko inú rẹ̀ run.+