Àìsáyà 66:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Bí ìyá ṣe ń tu ọmọ rẹ̀ nínú,Bẹ́ẹ̀ ni màá máa tù yín nínú;+Ẹ sì máa rí ìtùnú torí Jerúsálẹ́mù.+