Jeremáyà 4:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wò ó! Ọ̀tá yóò wá bí òjò tó ṣú,Àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀ á sì wá bí ìjì.+ Àwọn ẹṣin rẹ̀ yára ju ẹyẹ idì lọ.+ A gbé, torí pé a ti di ahoro!
13 Wò ó! Ọ̀tá yóò wá bí òjò tó ṣú,Àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀ á sì wá bí ìjì.+ Àwọn ẹṣin rẹ̀ yára ju ẹyẹ idì lọ.+ A gbé, torí pé a ti di ahoro!