Jeremáyà 6:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 Wọ́n á di ọfà* àti ọ̀kọ̀* mú. Ìkà ni wọ́n, wọn ò sì lójú àánú. Ìró wọn dà bíi ti òkun,Wọ́n sì gun ẹṣin.+ Wọ́n to ara wọn bí àwọn jagunjagun láti bá ọ jà, ìwọ ọmọbìnrin Síónì.”
23 Wọ́n á di ọfà* àti ọ̀kọ̀* mú. Ìkà ni wọ́n, wọn ò sì lójú àánú. Ìró wọn dà bíi ti òkun,Wọ́n sì gun ẹṣin.+ Wọ́n to ara wọn bí àwọn jagunjagun láti bá ọ jà, ìwọ ọmọbìnrin Síónì.”