Mátíù 27:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Wọ́n wá kan àwọn olè méjì mọ́gi lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀, ọ̀kan ní ọ̀tún rẹ̀ àti ọ̀kan ní òsì rẹ̀.+