Àìsáyà 9:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Àkóso* rẹ̀ á máa gbilẹ̀ títí lọ,Àlàáfíà kò sì ní lópin,+Lórí ìtẹ́ Dáfídì+ àti lórí ìjọba rẹ̀,Kó lè fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+ kó sì gbé e ró,Nípasẹ̀ ìdájọ́+ tí ó tọ́ àti òdodo,+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé. Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa ṣe èyí. 1 Tímótì 6:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 ẹnì kan ṣoṣo tó ní àìkú,+ ẹni tó ń gbé inú ìmọ́lẹ̀ tí kò ṣeé sún mọ́,+ tí èèyàn kankan kò rí rí, tí wọn ò sì lè rí.+ Òun ni kí ọlá àti agbára ayérayé jẹ́ tirẹ̀. Àmín.
7 Àkóso* rẹ̀ á máa gbilẹ̀ títí lọ,Àlàáfíà kò sì ní lópin,+Lórí ìtẹ́ Dáfídì+ àti lórí ìjọba rẹ̀,Kó lè fìdí rẹ̀ múlẹ̀ gbọn-in,+ kó sì gbé e ró,Nípasẹ̀ ìdájọ́+ tí ó tọ́ àti òdodo,+Láti ìsinsìnyí lọ àti títí láé. Ìtara Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa ṣe èyí.
16 ẹnì kan ṣoṣo tó ní àìkú,+ ẹni tó ń gbé inú ìmọ́lẹ̀ tí kò ṣeé sún mọ́,+ tí èèyàn kankan kò rí rí, tí wọn ò sì lè rí.+ Òun ni kí ọlá àti agbára ayérayé jẹ́ tirẹ̀. Àmín.