Àìsáyà 49:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Àwọn ọmọ tí wọ́n bí nígbà tí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀ ọ́ máa sọ ní etí rẹ pé,‘Ibí yìí ti há jù fún mi. Wá àyè fún mi, kí n lè máa gbé ibí.’+
20 Àwọn ọmọ tí wọ́n bí nígbà tí ọ̀fọ̀ ṣẹ̀ ọ́ máa sọ ní etí rẹ pé,‘Ibí yìí ti há jù fún mi. Wá àyè fún mi, kí n lè máa gbé ibí.’+