Àìsáyà 33:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Wo Síónì, ìlú àwọn àjọyọ̀ wa!+ Ojú rẹ máa rí Jerúsálẹ́mù bí ibùgbé tó pa rọ́rọ́,Àgọ́ tí wọn ò ní kó kúrò.+ Wọn ò ní fa àwọn èèkàn àgọ́ rẹ̀ yọ láé,Wọn ò sì ní já ìkankan nínú àwọn okùn rẹ̀.
20 Wo Síónì, ìlú àwọn àjọyọ̀ wa!+ Ojú rẹ máa rí Jerúsálẹ́mù bí ibùgbé tó pa rọ́rọ́,Àgọ́ tí wọn ò ní kó kúrò.+ Wọn ò ní fa àwọn èèkàn àgọ́ rẹ̀ yọ láé,Wọn ò sì ní já ìkankan nínú àwọn okùn rẹ̀.