Àìsáyà 61:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Dípò ìtìjú, ẹ máa ní ìpín ìlọ́po méjì,Dípò ìdójútì, wọ́n máa kígbe ayọ̀ nítorí ìpín wọn. Àní, ìpín ìlọ́po méjì ni wọ́n máa gbà ní ilẹ̀ wọn.+ Wọ́n á máa yọ̀ títí ayérayé.+
7 Dípò ìtìjú, ẹ máa ní ìpín ìlọ́po méjì,Dípò ìdójútì, wọ́n máa kígbe ayọ̀ nítorí ìpín wọn. Àní, ìpín ìlọ́po méjì ni wọ́n máa gbà ní ilẹ̀ wọn.+ Wọ́n á máa yọ̀ títí ayérayé.+