Àìsáyà 29:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Jèhófà sọ pé: “Àwọn èèyàn yìí ń fi ẹnu wọn sún mọ́ mi,Wọ́n sì ń fi ètè wọn bọlá fún mi,+Àmọ́ ọkàn wọn jìnnà gan-an sí mi;Àṣẹ èèyàn tí wọ́n kọ́ wọn ló sì ń mú kí wọ́n máa bẹ̀rù mi.+
13 Jèhófà sọ pé: “Àwọn èèyàn yìí ń fi ẹnu wọn sún mọ́ mi,Wọ́n sì ń fi ètè wọn bọlá fún mi,+Àmọ́ ọkàn wọn jìnnà gan-an sí mi;Àṣẹ èèyàn tí wọ́n kọ́ wọn ló sì ń mú kí wọ́n máa bẹ̀rù mi.+