43 nígbà náà, kí o fetí sílẹ̀ láti ọ̀run, ibi tí ò ń gbé,+ kí o sì ṣe gbogbo ohun tí àjèjì náà béèrè lọ́wọ́ rẹ, kí gbogbo aráyé lè mọ orúkọ rẹ, kí wọ́n sì máa bẹ̀rù rẹ,+ bí àwọn èèyàn rẹ Ísírẹ́lì ti ń ṣe, kí wọ́n sì mọ̀ pé a ti fi orúkọ rẹ pe ilé tí mo kọ́ yìí.