Jeremáyà 12:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Lójú mi, ogún mi ti dà bí ẹyẹ aṣọdẹ tó ní oríṣiríṣi àwọ̀;*Àwọn ẹyẹ aṣọdẹ míì yí i ká, wọ́n sì bá a jà.+ Ẹ wá, ẹ kóra jọ, gbogbo ẹ̀yin ẹran inú igbó,Ẹ wá jẹun.+
9 Lójú mi, ogún mi ti dà bí ẹyẹ aṣọdẹ tó ní oríṣiríṣi àwọ̀;*Àwọn ẹyẹ aṣọdẹ míì yí i ká, wọ́n sì bá a jà.+ Ẹ wá, ẹ kóra jọ, gbogbo ẹ̀yin ẹran inú igbó,Ẹ wá jẹun.+