Jeremáyà 6:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 “Látorí ẹni kékeré títí dórí ẹni ńlá, kálukú wọn ń jẹ èrè tí kò tọ́;+Látorí wòlíì títí dórí àlùfáà, kálukú wọn ń lu jìbìtì.+ 14 Wọ́n sì ń wo àárẹ̀* àwọn èèyàn mi sàn láàbọ̀,* wọ́n ń sọ pé,‘Àlàáfíà wà! Àlàáfíà wà!’ Nígbà tí kò sí àlàáfíà.+ Ìsíkíẹ́lì 13:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Kò sí wòlíì mọ́ ní Ísírẹ́lì, àwọn tó ń sọ tẹ́lẹ̀ fún Jerúsálẹ́mù, tí wọ́n ń rí ìran àlàáfíà fún un, nígbà tí kò sí àlàáfíà,”’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.
13 “Látorí ẹni kékeré títí dórí ẹni ńlá, kálukú wọn ń jẹ èrè tí kò tọ́;+Látorí wòlíì títí dórí àlùfáà, kálukú wọn ń lu jìbìtì.+ 14 Wọ́n sì ń wo àárẹ̀* àwọn èèyàn mi sàn láàbọ̀,* wọ́n ń sọ pé,‘Àlàáfíà wà! Àlàáfíà wà!’ Nígbà tí kò sí àlàáfíà.+
16 Kò sí wòlíì mọ́ ní Ísírẹ́lì, àwọn tó ń sọ tẹ́lẹ̀ fún Jerúsálẹ́mù, tí wọ́n ń rí ìran àlàáfíà fún un, nígbà tí kò sí àlàáfíà,”’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.