Àìsáyà 1:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Akọ màlúù mọ ẹni tó ra òun dunjú,Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì mọ ibùjẹ ẹran olówó rẹ̀;Àmọ́ Ísírẹ́lì ò mọ̀ mí,*+Àwọn èèyàn mi ò fi òye hùwà.” Jeremáyà 2:32 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 Ǹjẹ́ wúńdíá lè gbàgbé ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀,Àbí ìyàwó lè gbàgbé ọ̀já ìgbàyà* rẹ̀? Síbẹ̀, àwọn èèyàn mi ti gbàgbé mi tipẹ́tipẹ́.+ Jeremáyà 9:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Wọ́n tẹ ahọ́n wọn bí ọrun;Èké ṣíṣe ló gba ilẹ̀ náà kan, kì í ṣe òtítọ́.+ “Wọ́n ń tinú ibi bọ́ sínú ibi,Wọn ò sì kà mí sí,”+ ni Jèhófà wí.
3 Akọ màlúù mọ ẹni tó ra òun dunjú,Kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ sì mọ ibùjẹ ẹran olówó rẹ̀;Àmọ́ Ísírẹ́lì ò mọ̀ mí,*+Àwọn èèyàn mi ò fi òye hùwà.”
32 Ǹjẹ́ wúńdíá lè gbàgbé ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀,Àbí ìyàwó lè gbàgbé ọ̀já ìgbàyà* rẹ̀? Síbẹ̀, àwọn èèyàn mi ti gbàgbé mi tipẹ́tipẹ́.+
3 Wọ́n tẹ ahọ́n wọn bí ọrun;Èké ṣíṣe ló gba ilẹ̀ náà kan, kì í ṣe òtítọ́.+ “Wọ́n ń tinú ibi bọ́ sínú ibi,Wọn ò sì kà mí sí,”+ ni Jèhófà wí.