Jóòbù 8:13, 14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí gbogbo àwọn tó gbàgbé Ọlọ́run nìyẹn,*Torí ìrètí ẹni tí kò mọ Ọlọ́run* máa ṣègbé,14 Ẹni tí ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ̀ já sí asán,Tí ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ̀ ò sì lágbára, àfi bí òwú* aláǹtakùn.
13 Ohun tó máa ṣẹlẹ̀ sí gbogbo àwọn tó gbàgbé Ọlọ́run nìyẹn,*Torí ìrètí ẹni tí kò mọ Ọlọ́run* máa ṣègbé,14 Ẹni tí ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ̀ já sí asán,Tí ìgbẹ́kẹ̀lé rẹ̀ ò sì lágbára, àfi bí òwú* aláǹtakùn.