Àìsáyà 1:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Torí náà, Olúwa tòótọ́, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,Alágbára Ísírẹ́lì, kéde pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Mi ò ní fàyè gba àwọn elénìní mi mọ́,Màá sì gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá mi.+ Ìdárò 4:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Jèhófà ti fi ìrunú rẹ̀ hàn;Ó ti da ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná jáde.+ Ó sì ti dá iná kan ní Síónì tó jó ìpìlẹ̀ rẹ̀ run.+ Ìsíkíẹ́lì 5:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Mi ò sì ní bínú mọ́, inú mi ò ní ru sí wọn mọ́, màá ti tẹ́ ara mi lọ́rùn.+ Nígbà tí mo bá ti bínú gidigidi sí wọn tán, wọ́n á mọ̀ pé èmi, Jèhófà, ti sọ pé èmi nìkan ni mo fẹ́ kí ẹ máa jọ́sìn.+
24 Torí náà, Olúwa tòótọ́, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,Alágbára Ísírẹ́lì, kéde pé: “Ó tó gẹ́ẹ́! Mi ò ní fàyè gba àwọn elénìní mi mọ́,Màá sì gbẹ̀san lára àwọn ọ̀tá mi.+
11 Jèhófà ti fi ìrunú rẹ̀ hàn;Ó ti da ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná jáde.+ Ó sì ti dá iná kan ní Síónì tó jó ìpìlẹ̀ rẹ̀ run.+
13 Mi ò sì ní bínú mọ́, inú mi ò ní ru sí wọn mọ́, màá ti tẹ́ ara mi lọ́rùn.+ Nígbà tí mo bá ti bínú gidigidi sí wọn tán, wọ́n á mọ̀ pé èmi, Jèhófà, ti sọ pé èmi nìkan ni mo fẹ́ kí ẹ máa jọ́sìn.+