Hágáì 2:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 “‘Ògo tí ilé yìí máa ní yóò ju ti tẹ́lẹ̀ lọ,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. “‘Èmi yóò sì fún yín ní àlàáfíà ní ibí yìí,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.”
9 “‘Ògo tí ilé yìí máa ní yóò ju ti tẹ́lẹ̀ lọ,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. “‘Èmi yóò sì fún yín ní àlàáfíà ní ibí yìí,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.”