Àìsáyà 62:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Wọ́n máa pè wọ́n ní àwọn èèyàn mímọ́, àwọn tí Jèhófà tún rà,+A sì máa pè ọ́ ní Ẹni Tí A Wá, Ìlú Tí A Kò Pa Tì.+
12 Wọ́n máa pè wọ́n ní àwọn èèyàn mímọ́, àwọn tí Jèhófà tún rà,+A sì máa pè ọ́ ní Ẹni Tí A Wá, Ìlú Tí A Kò Pa Tì.+